• 转发
  • 反馈

《Bahia》歌词


歌曲: Bahia

所属专辑:Black Ivory Soul

歌手: Angelique Kidjo

时长: 03:32

播放 下载lrc歌词 下载纯文本歌词

Bahia

Bahia (巴伊亚) - Angelique Kidjo[00:00:00]

Aburo orè ni gbogbowa ewa ka lolé[00:00:06]

Aburo ibi kan ni wao kamura si ifè[00:00:15]

Ouidah ni ilé ti bahia[00:00:25]

Ti émin mon wa ri yin lénin o[00:00:29]

Bahia bahia bahia bahia bahia bahia [00:00:46]

Ilé ti babawa djinan awa fè lolé[00:01:06]

Bahia ilou ti awa lenin okpè gan si ilé[00:01:11]

Ogun ti awon agbalagba shé kalè foun wa o[00:01:17]

Logbé wa lo si bahia gbé gbogbowa kpo[00:01:22]

Bahia bahia bahia bahia bahia bahia [00:01:26]

Odjo ikadé wa m'bowa o ti ale rira wa[00:01:47]

Ewa ka moura foun odjo yin ninou oyaya[00:01:52]

Oluwa foun wa ni ayé edjè ka du kpè[00:01:57]

Bahia kpa gbogbowa kpo iréti wa lonan[00:02:02]

Aburo orè ni gbogbowa ewa ka lolé[00:02:07]

Aburo ibi kan ni wao kamura si ifè[00:02:13]

Ouidah ni ilé ti bahia[00:02:18]

Ti émin mon wa ri yin lénin o[00:02:20]

Oré ifé ayé ilé oré ifé ayé ilé [00:02:26]

Aburo orè ni gbogbowa ewa ka lolé[00:02:49]

Aburo ibi kan ni wao kamura si ifè[00:02:53]

Ouidah ni ilé ti bahia[00:02:58]

Ti émin mon wa ri yin lénin o[00:03:01]

Oré ifé ayé ilé oré ifé ayé ilé[00:03:06]